I'm going to be sharing the Nigerian national anthem in Yoruba language:
VERSE 1
Dide eyin ara
Waka je ipe Naijiria
K'a fife sin 'le wa
Pel'okun at'igbagbo
Kise awon akoni wa,
ko mase ja s'asan
K'a sin t'okan tara
Ile t'ominira,
at'alaafia pelu iso'okan
VERSE 2
Olorun Eleda
To ipa ona wa
F'ona han asaaju
K'odo wa m'otito
K'ododo at'ife po sii
K'aye won je pipe
So won d'eni giga
K'alafia oun eto le
Joba ni 'le wa